Mostrando postagens com marcador ORIKI. Mostrar todas as postagens
Mostrando postagens com marcador ORIKI. Mostrar todas as postagens

quinta-feira, 17 de novembro de 2016

ÀDÚRÀ EGÚNGÚN

Recolhido e organizado por Thonny Hawany



Saudação: Gbogbo Mònríwo! Egun o!

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pè o,
Ẹgúngún o

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o

(Gbogbo mònríwo)

Ẹgúngún a yè, kíì ṣẹ́ bọ ọ̀run
Mo júbà rẹ̀ Ẹgúngún mònríwo

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o

A kíì dé wa ó, a kíì ẹ́ Ẹgúngún
Won gbogbo ará asíwájú awo
Won gbogbo aráalé asíwájú mi

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o

Mo pẹ̀ gbogbo ẹ̀nyin
Si fún mi ààbò àti ìrònlọ́wọ́
Agó, kìì ngbọ́ ekún ọmọ rẹ̀

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o

Ki o ma ta etí wéré
Bàbá awa ọmọ rẹ ni a npẹ̀ o

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o

Ki o sare wá jẹ́ wa o
Ki o gbọ́ ìwùre wá

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o

Má jẹ̀ a ríkú èwe
Má jẹ̀ a ríjà Èsú
Má jẹ̀ a ríjà Ògún
Má jẹ̀ a rija omi
Má jẹ̀ a rija Soponná

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o

Motumbá Bàbá Egungun

Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ilẹ̀ mo pẹ̀ o,
Ẹgúngún o

Tradução:

Terra, eu vos chamo!
Terra, eu vos chamo!
Ó Egúngún!

Terra, eu vos chamo!
Terra, eu vos chamo!
Ó Egúngún!

Todos os espíritos do mònriwo!

Egúngún sobrevive, a ele saudamos e cultuamos
Apresento-vos meus respeitos, ó espírito do maríwo.

Nós vos saudamos em sua chegada, saudamos Egúngún
A todos os ancestrais do culto
A todos os ancestrais da minha família

Todos os espírito do maríwo
Eu chamo vos todos para me protegerem
Perdoe ao ouvir o choro dos filhos

Responde rapidamente
Ó pai, somos teus filhos e te chamamos

Vem logo nos ouvir
Ouve nossas rezas

Livra-nos da mortalidade “infantil”
Proteja-nos da ira de Èsú
Proteja-nos da ira de Ògún
Proteja-nos da ira das águas
Proteja-nos da ira de Soponná

A benção pai Egungun

terça-feira, 1 de novembro de 2016

ORIKI ÈṢÙ

Recolhido e organizado por Thonny Hawany




Saudação: Láaróyè ! Èṣù láaróyè!

Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o 
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o 
Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o 
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o 
Èṣù láaróyè, Èṣù láaróyè
     Iyìn o, iyìn o Èsù n má gbọ̀ o
Èṣù (falar o nome do Èṣù)
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o 
Èsù ọ̀ta òrìṣà
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o 
Oṣètùrá ni l’orukọ bàbá mọ́ ọ́
Alágogo ijà l’orukọ íyá npẹ́ o
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o 
Èṣù Ọ̀dàrà, ọmọkùnrin Idọ́lófin
O lé sónsó sóri ori esẹ̀ ẹlẹ́sẹ̀
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o
 Kọ̀ jẹ́ kọ́ jẹ́ ki ẹni njẹ́ gbẹ e mi
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o
A kìì lówó lái mu ti Èṣù kúrò
A kìì láyọ̀ lái mu ti Èṣù Kúrò
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o
Aṣòntún ṣe òsì làì ní ìtìjú
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o
Èsù ápáta somo olómo lénu
O fi okúta dipò iyó
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o
Lóògemo òrun a nla kálu
Pàápa-wàrá, a túká máṣe ṣà
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o
Èṣù máṣe mi, omo elómiran ni o sé
Èṣù máse, Èṣù máse, Èṣù máse
     Iyìn o, iyìn o Èṣù n má gbọ̀ o
Èṣù escute o meu louvor!
     Èṣù escute o meu louvor!
Èṣù escute o meu louvor!
     Èṣù escute o meu louvor!
Salve Èṣù! Salve Èṣù!
     Èṣù escute o meu louvor!
Èṣù (falar o nome do Èṣù)
     Èṣù escute o meu louvor!
Èṣù, o primeiro entre os orixás
     Èṣù escute o meu louvor!
Oṣètùrá é o nome pelo qual é chamado pelo pai
Alágogo é o nome pelo qual é chamado pela mãe
     Èṣù escute o meu louvor!
Èṣù bondoso, filho da cidade de Idólófin
De cabeça pontiaguda, está sempre na retaguarda
     Èṣù escute o meu louvor!
Não come e também não permite que comamos
     Èṣù escute o meu louvor!
Quem tem riqueza deve reservar a parte de Èṣù
Quem tem felicidade deve reservar a parte de Èṣù
     Èṣù escute o meu louvor!
Ele fica dos dois lados sem constrangimento
     Èṣù escute o meu louvor!
Montanha de pedra que faz o filho falar o que não quer
Aquele que usa pedra em lugar de sal
     Èṣù escute o meu louvor!
Filho do céu cuja grandeza está em todos os lugares
Aquele que fragmenta o que não se pode nuca mais unir
     Èṣù escute o meu louvor!
Èsù não me faça mal, faça ao filho do outro
Èsù não me faça mal, não me faça mão, não me faça mal
     Èṣù escute o meu louvou!